Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Osun ti fidi rẹ mulẹ pe eeyan mẹfa lo padanu ẹmi wọn ninu rogbodiyan oṣelu to waye nibẹ lọjọ Aje. Ninu atẹjade kan lọjọ Iṣẹgun, ...