Èèyàn kan láti ìdílé náà ṣàlàyé fún BBC bí ìjàmbá iná náà ṣe gbẹ̀mí ẹ̀gbọ́n rẹ̀ àtàwọn ẹbí rẹ̀, tó fi mọ́ àwọn èèyàn mẹ́ta ...
"Èmi ni wọ́n kọ́kọ́ jí gbé kí ìjínigbé ilé ẹ̀kọ́ náà tó wáyé. Ọjọ́ mẹ́rin ni mo lò ní àhámọ́ wọn kí n tó móríbọ́ lọ́wọ́ wọn.